Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet Duplicate
audio
audioduration (s)
1.5
28.1
text
stringlengths
2
128
speaker_id
int64
1
1
pàtàkì ni igba ọgbẹlẹ nígbàtí iṣẹ oko din kù
1
bi eré bi àwàdà dákúdájí iná mọnàmọná bẹrẹ ni àsikò ìjọba sagari ni bi ọdún mẹtàlélọgbọn sẹhin
1
olóriawo ṣe iwadi lọdọ ifa pẹlú ọpẹlẹ rẹ o ṣe àlàyé pe ko si ọmọ mọ lọdọ òrìṣà ṣùgbọn nígbàtí
1
èrè awọn ìwà ìbàjẹ wọnyi ti ba ìlú jẹ èyi jẹ ikan ninu ohun ti ó dá kún ohun ti
1
ni ìlú ọba ìjọba pese ilé fún awọn abirùn ati aláìní ti o jẹ ọmọ onilu ati iranlọwọ miran lati
1
títí di bi ọgbọn ọdún sẹhin àti rí oúnjẹ yorùbá rà ṣọwọn
1
awọn onilù oníṣòwò ibile olórin ibile oniṣẹ ọna ati eléré ìbílẹ yorùbá ni ìlúọba pàdánù àti jẹ ọrọ àti polongo
1
ẹbí ìyàwó le sọ wípé ki ẹgbẹ wọ aṣọ aláwọ ewé lati ba ohun yọ ayọ ìgbéyàwó ki ẹbí ọkọ
1
bí a ti nṣe ní ilé wa ewọ ibòmíì
1
ni àyíká igbin àti ìwo rẹ a kó wọ karaun fún àbò
1
ìjọba njaya nítorí owó ti o nwọle kò kárí owó lati ṣe ọpọlọpọ ẹtọ ti àwọn ará ìlú nri gbà
1
ẹlẹdẹ rò pé ọrẹ ju owó lọ ó gbà lati yá àjàpá lówó nítorí àdéhùn rẹ
1
àwọn ará ìlú china ẹwẹ kò fi èdè wọn ṣeré rárá tó bẹẹ ti odindi ìlú america àti àwọn
1
ajá wọn ti pa ọbọ nítorí adájọ ti sọ stuart hall si ẹwọn oṣù mẹdogún
1
wọn tú jáde lati fi ọpọ dibò àti bójú tó ibò wọn lati gbé góminà ọgbẹni rauf arẹgbẹṣọlá padà
1
wà ni ipò àti bèrè ojú owó
1
ni àsikò yi ki ṣe pe iná ti ilú pèsè kò tó ṣùgbọn a ṣe akiyesi pé awọn òṣìṣẹ ni
1
ohun fúnra rẹ tẹlé ọmọ rẹ iwin tún yọjú àwọn mejeeji sá eré padà si ìlú lai ranti gbé igbá
1
kó èlò bi ẹjà tútù tàbi gbigbẹ edé pọnmọ sinú ikòkò epopupa yi
1
ọrẹàánú ni ó ńlọ lọwọlọwọ
1
ori igbe ògì ti ó dànù ni àwọn ọmọ wa nígbàtí bàbá beyioṣe wọlé
1
ni ilu nla
1
nítorí ìfẹ owó ti ó gbòde láyé òde òní mu
1
di ìdájọ lọwọ ṣùgbọn apàniyàn olè alágbèrè àti bẹẹbẹẹ lọ pọ nínú òṣèlú nàíjíríà nítorí wọn kò ni ìtìjú
1
ẹfi ojú sọna lọsọsẹ fún kíkọ nípa àwọn nkan wọnyi lédè yorùbá àti ìtumọ lédè gẹẹsì ìmúlò òwe kíkọ èdè
1
ìkà ti wà ninú irú àwọn bayi ki wọn to gba ẹsìn wọn kan fi ẹsìn bojú ṣe ìkà ni
1
aṣọ ẹbí tún wa fún ẹbí àti ọmọ oloku ìyàwó ṣíṣe ẹgbẹ ìlú àti bẹẹbẹẹ lọ
1
ó yẹ – bi a bá lo ìmọ òṣìṣẹ fún irú iṣẹ ti wọn mọ á din àkókò àti
1
ọpọlọpọ òbí bayi ni òṣì má ta pa
1
ní ọjọ ẹti ọjọ keji lelogun oṣu keji ọdún yi ẹrọ amóhùn máwòrán iluọba tu asiri ọmọkùnrin kan ti o
1
òwe yorùbá ti ó ni ṣòkòtò àgbàwọ bi kò ṣoni lẹsẹ á fúnni nítan
1
bàbá tún dé ọdọ obinrin yi lati tu ninu o sọ fún pe bi eyi o ṣe omiran yio ṣe
1
dara ti wọn yio sọ ọmọ ni ọjọ ikómọ
1
ọlọ yi
1
àmọtékùn fi eré si ṣùgbọn gbogbo ọṣẹ ti ó wà ninu kànrìnkàn ti ta àbàwọn si ara rẹ lati ori
1
mọ
1
àwọn enia ti o ri wọn ni bàbá iwọ gun kẹtẹkẹtẹ ọmọ ńrin ni ilẹ
1
yorùbá ní ẹbẹ la mbẹ òṣìkà pé kí ó tú ìlú rẹ ṣe a bẹ àwọn òṣèlú ilẹ yorùbá ni
1
àti ọmọdé àti àgbà ló fẹrán àkàrà
1
ikeji fún ọpọlọpọ idi
1
pé ohun ri wípé ayé ti fẹ parẹ àwọn kan gbàgbọ wọn bẹrẹ si ta ohun ìní wọn
1
ọba olóyè ọlọrọ àti aláìní ilẹ yorùbá ló fẹràn àti rán ọmọ wọn lọ si iléiwé bi àwọn fúnra wọn
1
èkó ò ní bàjẹ o
1
lára nkan ti itàn yi kọ wa ni pé ohun ani là ńlò ibi ti à ńlọ ni ká dojú
1
ni ọjọ ẹti oṣù kẹfa ọjọ keje ọdún ẹgbẹrunméjìlemẹtala adájọ ṣe ìdájọ ẹwọn gbére fún ọpẹmipọ jaji ọmọ ọdún méjìdínlógún
1
ọmùtí gbàgbé ìṣẹ fún ìgbaì diẹ ni nítorí bí ọmùtí bá jí tán ìṣẹ rẹ kò tán
1
ẹyin ọmọ odùduwà ẹjẹ ki a ran rawa létí wípé ẹni tólèdè lóni ayé ibi ti wọn ti nsọ
1
ọkùnrin àti obìnrin mọ lọjọ òní ni ọjọ kan yorùbá orílẹ èdè nàíjíríà àti gbogbo ilẹ aláwọ dúdú yio ṣe
1
lẹhin ìgbéyàwó lati fi han wípé wọn ti di ara kan
1
ọpọlọpọ ayẹyẹ àti ìjọsìn ló mú ìlù orin ijó àti àsè dáni
1
òwe yorùbá kan tilẹ sọ wípé onígbá io npe igbá rẹ ni pankara ti a fi nbaa fi kolẹ
1
òwe yorùbá yi wúlò lati juwe òye àgbàlagbà lati wo ẹhìn fún ẹkọ nínú ìrírí tó ti kọjá lati yanjú
1
olóògbé ju ki gbogbo owó bẹẹ lọ fún ayẹyẹ
1
orí ti àjàpá yọ jade lati jẹ àkàrà ọsanyin fọ igi ẹlẹgun mọ lórí awọn ẹbi rẹ sálọ
1
lè fa ewu iyebíye nítorí náà ó dára ká kọ ọgbọn lati ọdọ àgbà
1
wọn gba ìdájọ èyí ti wọn ni lati lo ọgbọn ọdún ó kéré jù
1
bi àwọn ti ó ni ipò giga tabi òkìkí ni àwùjọ kò fẹ fẹ ìyàwó púpọ ará ilú á fi
1
yorùbá ni bi onilé bá ti ńfi àpárí iṣu lọ àlejò ilé tó lọ
1
àti michael adébọwálé tó kárí ayé
1
ọdọ miran a wọ asọ àti bàtà òtútù ninu ooru
1
orin yi ni olùkọ ma fi ńkọ àwọn ọmọ iléìwé alakọbẹrẹ nigbà iléìwé ọfẹ ti àwọn òṣèlú ilẹ yorùbá ti
1
ìròyìn jade pé mariam yahia ibrahim ti bi ọmọ si ẹwọn a ri ninú ẹbi rẹ ti o ke pe
1
àti ọsán àti òru ni ariwo ẹrọiná kékèké yi ma ńdá sílẹ ṣùgbọn èyí tó burú jù ni herehuru ti
1
ewédú dùn pẹlú gbẹgìrì tàbi ọbẹ ata lati fi jẹ ẹkọ àmàlà láfún àti ounjẹ òkèlè yókù bi ẹbà iyán
1
gẹgẹbi olóyè ọbafẹmi awolọwọ ti sọ nígbàtí wọn ńṣe àdéhùn fún ominira pe ominira ki ṣe ni ti orúkọ ilú
1
yorùbá ma nlo àwọn àròsọ itàn wọnyi lati kọ àwọn ọmọdé ni ẹkọ
1
ẹ fojú sọnà fún àwọn ọja yókù
1
ọrọ yorùbá sọ wípé ọwọ ọmọde ko to pẹpẹ tagbalagba ko wọ kèrègbè èyí tí a lè túmọ sí wípé
1
ó lè ṣe nkan ti ẹni kan kò ṣerí
1
àrùn ara tinumi aya aṣojúọba bẹrẹ si han nítorí ó sọ ìyàwó ọmọ rẹ di orogún
1
kó ọkẹ aimoye owó lati ṣe àjọyọ ìdàpọ ti ará ilú kò kópa ninu rẹ ló ṣe pàtàkì bi kò
1
ariwo sọ ṣùgbọn ìtìjú bo àjàpá
1
bẹ ewùrà yi
1
inú obinrin ti wọn fẹ ìyàwó tẹlé kò lè dùn dé inú nítorí eyi kò lè fi gbogbo ọkàn rẹ
1
yorùbá ni ohun tó yẹ ni lo yẹ ni òkùnkùn o yẹ ọmọ eniyan nítorí òkùnkùn ti iléiṣẹ mọnàmọná fa
1
eleyi jẹ ki yorùbá pọ kà kiri àgbáyé pàtàkì ni àríwá nàíjíríà
1
kò sí àyè fún ọmọ irú àwọn bayi lati mọ wọn lójú nítorí wọn o si nílé lati ṣe ojuṣe
1
títí di àsìkò yi ìwé na ngbayi si ni nítorí wọn ti túmọ ìwé yi sí èdè oriṣiriṣi
1
ẹkọ wọnyi a lè fi bá ẹni ti ó bá jọ ara rẹ lójú wi aimọ iwọn ara ẹni léwu
1
ẹkọ àjòjì eyi yi ni èdè gẹẹsi
1
ààntére lọ fọ abọ lódò
1
ìwà oriṣiriṣi ni ó ma ńhàn ni ilé olórogún àrùn ìyàwó ti ó ńjalè purọ ṣe àgbèrè aláisàn ti ó
1
títí dé òkèòkun
1
ni ìlú èkó sunkẹrẹ fakẹrẹ ọkọ ko jẹ ki obi tètè délé lẹhin iṣẹ ojọ wọn ẹlo miran ti ji
1
fún idi eyi yorùbá ẹ jẹ ki á ronú lati ṣe àyipadà
1
o ṣeni lanu wipe ko si àsọ tẹl tabi ipalẹmọ fún ará ìlú ati ijọba
1
àṣepọ laarin ará ìlúọba àti yorùbá ti lè ni ọgọrun ọdún nítorí eyi kò si ibi ti enia dé ni
1
yorùbá
1
bí ìjọba ẹbí àti ará ti ṣe ìkìlọ tó nípa ọtí àmunpara bi o ti ngba etí ọtun wọlé lo
1
nígbàtí bàbá ti gbìyànjú titi ti kò mọ ohun ti ó tún lè ṣe mọ lati tẹ aiyé lọrùn ni
1
a le lo òwe yi lati kilọ fun ẹni to fẹ lọ si òkèòkun lọna kọna lai ni ase tabi
1
ọrọ yorùbá ni àlébù ki ṣe ẹgàn tàbi agọ ṣùgbọn ẹgàn àti agọ ni fún ẹni ti ojú rẹ fọ
1
àwọn òṣèlú tó yẹ ki wọn gbé èdè ìlú wọn lárugẹ n dá kún pí pa èdè rẹ
1
nígbàtí ọjọ ti àjàpá dá pé ẹlẹdẹ reti titi ki ó wá san owó ti ó yá ṣùgbọn àjàpá kò
1
ẹbẹ là ńbẹ òṣìkà ki ó tú ìlú rẹ ṣe nítorí eyi a bẹ ìjọba àti àwọn gómìnà pé ki
1
nkankan lọ ti ayé bá parẹ nitotọ
1
kò tán
1
ọlá ninú orúkọ yorùbá ki ṣe owó àti ohun ini nikan yorùbá ka ilera si ọlà
1
mofẹ dàgbà lati fẹ obinrin
1
ohun gbogbo níwọntúnwọnsìn ọtí àmunpara kò yẹ ọmọ ènìà
1
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
22